Bacause of you. I dey live, I dey breath, I dey eat
So, I wanna have some talk with you
Orun, silekun I wanna have some talk, [with] you o (2xe)
Nitori re mose n lola
Nitori re mose n s'oge
Nitori re mose n ra moto
Mowole, M'oboluwa mi soro
Nitori re mose wa laye
Nitori re mose n woso sara
Nitori re moji l'owuro
Mow'aye mi lode ye
A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Nitori re mose n gbo iroyin ayo
Lais'owo laisi nkankan
Iya oni, layoola o
B'oluwa tiwi, be naa lori
Jiji moji lowuro
Moji si inu ipese re
Ayo at'alafia ye ye
O, o o oni pe ki n ma se beru
A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Melo la fe so
Melo lo si n bowa
Melo la fe so, eh
Melo lo si n bowa
Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
Ninu iponju, Ninu idamu,
B'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro
B'emi o le yan
Baye ba foju dimi
B'emi o le ni
Mawole, maboluwa mi soro
A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Ninu iponju, Ninu idamu,
B'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro
Mioni foju sunkun mo o
Aye loja, oh oh... Orun... Orunile
And that's fine by me... Eh eh...
Oh... Ye ye... Bring it down... Oh oh...
Everyday, so God... Bacause of you. I dey live, I dey breath, I dey eat So, I wanna have some talk with you Orun, silekun I wanna have some talk, [with] you o (2xe) Nitori re mose n lola Nitori re mose n s'oge Nitori re mose n ra moto Mowole, M'oboluwa mi soro Nitori re mose wa laye Nitori re mose n woso sara Nitori re moji l'owuro Mow'aye mi lode ye A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o Mowole, M'obolowa mi soro Nitori re mose n gbo iroyin ayo Lais'owo laisi nkankan Iya oni, layoola o B'oluwa tiwi, be naa lori Jiji moji lowuro Moji si inu ipese re Ayo at'alafia ye ye O, o o oni pe ki n ma se beru A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o Mowole, M'obolowa mi soro Melo la fe so Melo lo si n bowa Melo la fe so, eh Melo lo si n bowa Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh Ninu iponju, Ninu idamu, B'ebi ba n p'ona Mawole, maboluwa mi soro B'emi o le yan Baye ba foju dimi B'emi o le ni Mawole, maboluwa mi soro A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o Mowole, M'obolowa mi soro Ninu iponju, Ninu idamu, B'ebi ba n p'ona Mawole, maboluwa mi soro Mioni foju sunkun mo o Aye loja, oh oh... Orun... Orunile And that's fine by me... Eh eh... Oh... Ye ye... Bring it down... Oh oh... Explain Request ×
Lyrics taken from
/lyrics/a/asa/iba.html